Di aṣojú Niki POS
Ẹ ran àwọn ṣọ́ọ̀bù tó wà nítòsí yín lọ́wọ́ láti bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Niki POS. Ṣọ́ọ̀bù tó bá forúkọsílẹ̀ pẹ̀lú kóòdù aṣojú yín jẹ́ tiyín fún oṣù 12 àkọ́kọ́ tí wọ́n bá sanwó, ẹ ó sì jèrè 30% nínú ohun tó bá dé ọ̀dọ̀ wa láti inú ìsanwó wọn kọ̀ọ̀kan, tí a ó san lóṣooṣù pẹ̀lú bank transfer.
A ó pè yín lórí WhatsApp láti jẹ́rìísí ẹni tí ẹ jẹ́. A kò béèrè fọ́tò káàdì ìdánimọ̀ yín.
Ìforúkọsílẹ̀ kò tíì ṣí. Ẹ kọ̀wé sí wa ní support@nikipos.com.